Yunifásítì Kòlúmbíà


Yunifásítì Kòlúmbíà


Yunifásítì Kòlúmbíà (bákanáà bíi Kòlúmbíà, àti fún ìṣeṣẹ́ bíi Columbia University in the City of New York) ni is a yunifásítì aṣèwadìí aládàníi Ivy League ní New York City. Wọ́n da sílẹ̀ ní ọdún 1754 lórí ilẹ̀ Trinity Church ní Manhattan, Kòlúmbíà ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga tó pẹ́ jùlọ ní ìpínlẹ̀ New York àti èyí tó pẹ́ jùlọ kaàrún ní Amẹ́ríkà.

Ìtọ́kasí


Text submitted to CC-BY-SA license. Source: Yunifásítì Kòlúmbíà by Wikipedia (Historical)


Langue des articlesQuelques articles à proximité